-
Jóṣúà 14:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ìdí nìyẹn tí Hébúrónì fi jẹ́ ogún Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ọmọ Kénásì títí dòní, torí ó fi gbogbo ọkàn rẹ̀ tẹ̀ lé Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì.+
-
-
Jóṣúà 19:49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Bí wọ́n ṣe pín àwọn ilẹ̀ tí wọ́n jogún náà tán nìyí gẹ́gẹ́ bí àwọn ìlú tó wà níbẹ̀. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá fún Jóṣúà ọmọ Núnì ní ogún láàárín wọn.
-