-
Ẹ́kísódù 29:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 “Ohun tí ìwọ yóò fi rúbọ lórí pẹpẹ náà nìyí: ọmọ àgbò méjì tó jẹ́ ọlọ́dún kan lójoojúmọ́ títí lọ.+
-
-
Léfítíkù 6:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 “Pàṣẹ fún Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pé, ‘Òfin ẹbọ sísun+ nìyí: Kí ẹbọ sísun wà nínú ààrò lórí pẹpẹ ní gbogbo òru mọ́jú, kí iná sì máa jó lórí pẹpẹ náà.
-
-
Ìsíkíẹ́lì 46:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Kí wọ́n máa pèsè akọ ọ̀dọ́ àgùntàn, ọrẹ ọkà àti òróró ní àràárọ̀ láti fi ṣe odindi ẹbọ sísun déédéé.’
-