Ẹ́sírà 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, wọ́n ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà gẹ́gẹ́ bí ohun tó wà lákọsílẹ̀,+ ojoojúmọ́ ni wọ́n sì máa ń rú iye ẹbọ sísun tó yẹ kí wọ́n rú lọ́jọ́ kọ̀ọ̀kan.+
4 Lẹ́yìn náà, wọ́n ṣe Àjọyọ̀ Àtíbàbà gẹ́gẹ́ bí ohun tó wà lákọsílẹ̀,+ ojoojúmọ́ ni wọ́n sì máa ń rú iye ẹbọ sísun tó yẹ kí wọ́n rú lọ́jọ́ kọ̀ọ̀kan.+