-
Jẹ́nẹ́sísì 48:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ó sì súre fún wọn ní ọjọ́+ yẹn, ó ní:
“Kí Ísírẹ́lì máa fi orúkọ rẹ súre pé,
‘Kí Ọlọ́run mú kí o dà bí Éfúrémù àti Mánásè.’”
Ó wá ń fi Éfúrémù ṣáájú Mánásè.
-