1 Kọ́ríńtì 11:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́ mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé orí gbogbo ọkùnrin ni Kristi; + bákan náà, orí obìnrin ni ọkùnrin;+ bákan náà, orí Kristi ni Ọlọ́run.+ 1 Pétérù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bákan náà, kí ẹ̀yin aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ kó lè jẹ́ pé, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tí kò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà, a máa lè jèrè wọn nípasẹ̀ ìwà àwọn aya wọn+ láìsọ ohunkóhun,
3 Àmọ́ mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ pé orí gbogbo ọkùnrin ni Kristi; + bákan náà, orí obìnrin ni ọkùnrin;+ bákan náà, orí Kristi ni Ọlọ́run.+
3 Bákan náà, kí ẹ̀yin aya máa tẹrí ba fún àwọn ọkọ yín,+ kó lè jẹ́ pé, tí a bá rí ẹnikẹ́ni tí kò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà, a máa lè jèrè wọn nípasẹ̀ ìwà àwọn aya wọn+ láìsọ ohunkóhun,