Diutarónómì 23:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Tí o bá jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ má ṣe lọ́ra láti san án.+ Torí ó dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa béèrè rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ó máa di ẹ̀ṣẹ̀ sí ọ lọ́rùn.+
21 “Tí o bá jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ má ṣe lọ́ra láti san án.+ Torí ó dájú pé Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa béèrè rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ; àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ó máa di ẹ̀ṣẹ̀ sí ọ lọ́rùn.+