Nọ́ńbà 19:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Kí ọkùnrin kan tó mọ́ kó eérú màlúù+ náà jọ, kó sì kó o sí ibi tó mọ́ lẹ́yìn ibùdó, kí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tọ́jú rẹ̀, kí wọ́n sì máa bù ú sínú omi tí wọ́n á fi ṣe ìwẹ̀mọ́.+ Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.
9 “‘Kí ọkùnrin kan tó mọ́ kó eérú màlúù+ náà jọ, kó sì kó o sí ibi tó mọ́ lẹ́yìn ibùdó, kí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tọ́jú rẹ̀, kí wọ́n sì máa bù ú sínú omi tí wọ́n á fi ṣe ìwẹ̀mọ́.+ Ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ ni.