-
Nọ́ńbà 19:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Kí ẹni tó mọ́ náà wọ́n ọn sára aláìmọ́ náà ní ọjọ́ kẹta àti ní ọjọ́ keje,+ kó sì wẹ̀ ẹ́ mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ ní ọjọ́ keje; kó wá fọ aṣọ rẹ̀, kó sì fi omi wẹ̀, yóò sì di mímọ́ ní alẹ́.
20 “‘Àmọ́ tí ẹnì kan bá jẹ́ aláìmọ́, tí kò sì wẹ ara rẹ̀ mọ́, ṣe ni kí ẹ pa ẹni* náà kúrò láàárín ìjọ,+ torí ó ti sọ ibi mímọ́ Jèhófà di aláìmọ́. Aláìmọ́ ni torí wọn ò wọ́n omi ìwẹ̀mọ́ sí i lára.
-