Nọ́ńbà 21:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Mósè rán àwọn ọkùnrin kan lọ ṣe amí Jásérì.+ Wọ́n gba àwọn àrọko rẹ̀,* wọ́n sì lé àwọn Ámórì tí wọ́n wà níbẹ̀ kúrò.
32 Mósè rán àwọn ọkùnrin kan lọ ṣe amí Jásérì.+ Wọ́n gba àwọn àrọko rẹ̀,* wọ́n sì lé àwọn Ámórì tí wọ́n wà níbẹ̀ kúrò.