Nọ́ńbà 32:37, 38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì kọ́ Hẹ́ṣíbónì,+ Éléálè,+ Kíríátáímù,+ 38 Nébò+ àti Baali-méónì,+ wọ́n yí orúkọ àwọn ìlú náà pa dà, wọ́n kọ́ Síbúmà; wọ́n sì sọ àwọn ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ míì.
37 Àwọn ọmọ Rúbẹ́nì kọ́ Hẹ́ṣíbónì,+ Éléálè,+ Kíríátáímù,+ 38 Nébò+ àti Baali-méónì,+ wọ́n yí orúkọ àwọn ìlú náà pa dà, wọ́n kọ́ Síbúmà; wọ́n sì sọ àwọn ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ míì.