Ẹ́kísódù 26:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Kí o fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa tí wọ́n hun pọ̀ ṣe aṣọ* tí ẹ máa ta sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà.+
36 Kí o fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa tí wọ́n hun pọ̀ ṣe aṣọ* tí ẹ máa ta sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ náà.+