Jóṣúà 11:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Jóṣúà wá gba gbogbo ilẹ̀ náà, bí Jèhófà ṣe ṣèlérí fún Mósè,+ Jóṣúà sì fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì, bí ìpín wọn, pé kí wọ́n pín in láàárín àwọn ẹ̀yà wọn.+ Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+ Jóṣúà 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+ Sáàmù 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+
23 Jóṣúà wá gba gbogbo ilẹ̀ náà, bí Jèhófà ṣe ṣèlérí fún Mósè,+ Jóṣúà sì fi ṣe ogún fún Ísírẹ́lì, bí ìpín wọn, pé kí wọ́n pín in láàárín àwọn ẹ̀yà wọn.+ Ogun sì dáwọ́ dúró ní ilẹ̀ náà.+
18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+
2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+