ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 22:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jèhófà Ọlọ́run yín ti wá fún àwọn arákùnrin yín ní ìsinmi, bó ṣe ṣèlérí fún wọn.+ Torí náà, ẹ lè pa dà sí àgọ́ yín ní ilẹ̀ tí Mósè ìránṣẹ́ Jèhófà fún yín pé kí ẹ jogún ní òdìkejì* Jọ́dánì.+

  • Jóṣúà 22:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Rúbẹ́nì, àwọn ọmọ Gádì àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè kúrò lọ́dọ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yòókù, ní Ṣílò, ní ilẹ̀ Kénáánì, wọ́n sì pa dà sí ilẹ̀ Gílíádì,+ ilẹ̀ tí wọ́n jogún tí wọ́n sì ń gbé bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́