Jóṣúà 22:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mósè ti fún ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè ní ogún ní Báṣánì,+ Jóṣúà sì ti fún ààbọ̀ ẹ̀yà náà tó kù àti àwọn arákùnrin wọn ní ilẹ̀ ní ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì.+ Bákan náà, nígbà tí Jóṣúà ní kí wọ́n máa lọ sí àgọ́ wọn, ó súre fún wọn,
7 Mósè ti fún ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè ní ogún ní Báṣánì,+ Jóṣúà sì ti fún ààbọ̀ ẹ̀yà náà tó kù àti àwọn arákùnrin wọn ní ilẹ̀ ní ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì.+ Bákan náà, nígbà tí Jóṣúà ní kí wọ́n máa lọ sí àgọ́ wọn, ó súre fún wọn,