-
Àwọn Onídàájọ́ 8:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Gídíónì gòkè gba ọ̀nà àwọn tó ń gbé inú àgọ́ ní ìlà oòrùn Nóbà àti Jógíbéhà,+ ó sì gbógun ja ibùdó náà nígbà tí wọn ò fura.
-