Nọ́ńbà 26:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn ọmọ Mánásè+ nìyí: látọ̀dọ̀ Mákírù,+ ìdílé àwọn ọmọ Mákírù; Mákírù wá bí Gílíádì;+ látọ̀dọ̀ Gílíádì, ìdílé àwọn ọmọ Gílíádì.
29 Àwọn ọmọ Mánásè+ nìyí: látọ̀dọ̀ Mákírù,+ ìdílé àwọn ọmọ Mákírù; Mákírù wá bí Gílíádì;+ látọ̀dọ̀ Gílíádì, ìdílé àwọn ọmọ Gílíádì.