ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Mo tún ti fún ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ ní ibi tó ṣẹ́ kù ní Gílíádì àti gbogbo Báṣánì tó jẹ́ ilẹ̀ ọba Ógù. Gbogbo agbègbè Ágóbù, tó jẹ́ ti Báṣánì, ni wọ́n mọ̀ sí ilẹ̀ àwọn Réfáímù.

  • Jóṣúà 13:31
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 Ìdajì Gílíádì pẹ̀lú Áṣítárótì àti Édíréì,+ àwọn ìlú tó wà ní ilẹ̀ ọba Ógù ní Báṣánì, di ti àwọn ọmọ Mákírù,+ ọmọ Mánásè, ìyẹn ìdajì àwọn ọmọ Mákírù ní ìdílé-ìdílé.

  • Jóṣúà 17:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Kèké+ wá mú ẹ̀yà Mánásè,+ torí òun ni àkọ́bí Jósẹ́fù.+ Torí pé ọkùnrin ogun ni Mákírù+ àkọ́bí Mánásè, tó sì jẹ́ bàbá Gílíádì, ó gba Gílíádì àti Báṣánì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́