Ẹ́kísódù 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Torí náà, Ọlọ́run mú kí àwọn èèyàn náà lọ yí gba ọ̀nà aginjù tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òkun Pupa.+ Ṣe ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ nígbà tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.
18 Torí náà, Ọlọ́run mú kí àwọn èèyàn náà lọ yí gba ọ̀nà aginjù tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òkun Pupa.+ Ṣe ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́ nígbà tí wọ́n kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.