Jóṣúà 24:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nígbà tó yá, mo rán Mósè àti Áárónì,+ mo sì fi ohun tí mo ṣe láàárín wọn mú ìyọnu bá Íjíbítì,+ mo sì mú yín jáde. 1 Sámúẹ́lì 12:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Gbàrà tí Jékọ́bù dé sí Íjíbítì,+ tí àwọn baba ńlá yín sì bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ Jèhófà rán Mósè+ àti Áárónì, kí wọ́n lè mú àwọn baba ńlá yín jáde kúrò ní Íjíbítì, kí wọ́n sì mú kí wọ́n máa gbé ibí yìí.+
5 Nígbà tó yá, mo rán Mósè àti Áárónì,+ mo sì fi ohun tí mo ṣe láàárín wọn mú ìyọnu bá Íjíbítì,+ mo sì mú yín jáde.
8 “Gbàrà tí Jékọ́bù dé sí Íjíbítì,+ tí àwọn baba ńlá yín sì bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe Jèhófà fún ìrànlọ́wọ́,+ Jèhófà rán Mósè+ àti Áárónì, kí wọ́n lè mú àwọn baba ńlá yín jáde kúrò ní Íjíbítì, kí wọ́n sì mú kí wọ́n máa gbé ibí yìí.+