Nọ́ńbà 9:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìgbàkígbà tí ìkùukùu náà bá kúrò lórí àgọ́ náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì á gbéra+ kíákíá, ibi tí ìkùukùu náà bá sì dúró sí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa pàgọ́+ sí.
17 Ìgbàkígbà tí ìkùukùu náà bá kúrò lórí àgọ́ náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì á gbéra+ kíákíá, ibi tí ìkùukùu náà bá sì dúró sí ni àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa pàgọ́+ sí.