Diutarónómì 10:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 “Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbéra ní Béérótì Bene-jáákánì lọ sí Mósírà. Ibẹ̀ ni Áárónì kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí,+ Élíásárì ọmọ rẹ̀ wá di àlùfáà dípò rẹ̀.+
6 “Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbéra ní Béérótì Bene-jáákánì lọ sí Mósírà. Ibẹ̀ ni Áárónì kú sí, ibẹ̀ sì ni wọ́n sin ín sí,+ Élíásárì ọmọ rẹ̀ wá di àlùfáà dípò rẹ̀.+