Diutarónómì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí náà, a gba ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin wa kọjá, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì, a ò gba ọ̀nà Árábà, Élátì àti Esioni-gébérì.+ “A wá yí gba ọ̀nà aginjù Móábù.+ 1 Àwọn Ọba 9:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ọba Sólómọ́nì tún ṣe ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun ní Esioni-gébérì,+ tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Élótì, ní èbúté Òkun Pupa ní ilẹ̀ Édómù.+
8 Torí náà, a gba ọ̀dọ̀ àwọn arákùnrin wa kọjá, àwọn àtọmọdọ́mọ Ísọ̀,+ tí wọ́n ń gbé ní Séírì, a ò gba ọ̀nà Árábà, Élátì àti Esioni-gébérì.+ “A wá yí gba ọ̀nà aginjù Móábù.+
26 Ọba Sólómọ́nì tún ṣe ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun ní Esioni-gébérì,+ tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Élótì, ní èbúté Òkun Pupa ní ilẹ̀ Édómù.+