Nọ́ńbà 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bí wọ́n ṣe ń bá ìrìn àjò wọn lọ láti Òkè Hóórì,+ wọ́n gba ọ̀nà Òkun Pupa kọjá, kí wọ́n lè lọ gba ẹ̀yìn ilẹ̀ Édómù,+ ìrìn àjò náà sì tán àwọn èèyàn náà* lókun.
4 Bí wọ́n ṣe ń bá ìrìn àjò wọn lọ láti Òkè Hóórì,+ wọ́n gba ọ̀nà Òkun Pupa kọjá, kí wọ́n lè lọ gba ẹ̀yìn ilẹ̀ Édómù,+ ìrìn àjò náà sì tán àwọn èèyàn náà* lókun.