Jóṣúà 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù. Jóṣúà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ilẹ̀ tí wọ́n fi kèké pín*+ fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù+ bẹ̀rẹ̀ láti Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò dé ibi omi tó wà lápá ìlà oòrùn Jẹ́ríkò, ó gba inú aginjù láti Jẹ́ríkò lọ sí agbègbè olókè Bẹ́tẹ́lì.+ Jóṣúà 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kèké mú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, ilẹ̀ tí wọ́n sì fi kèké pín fún wọn wà láàárín àwọn èèyàn Júdà+ àtàwọn èèyàn Jósẹ́fù.+
15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù.
16 Ilẹ̀ tí wọ́n fi kèké pín*+ fún àwọn àtọmọdọ́mọ Jósẹ́fù+ bẹ̀rẹ̀ láti Jọ́dánì ní Jẹ́ríkò dé ibi omi tó wà lápá ìlà oòrùn Jẹ́ríkò, ó gba inú aginjù láti Jẹ́ríkò lọ sí agbègbè olókè Bẹ́tẹ́lì.+
11 Kèké mú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, ilẹ̀ tí wọ́n sì fi kèké pín fún wọn wà láàárín àwọn èèyàn Júdà+ àtàwọn èèyàn Jósẹ́fù.+