Jóṣúà 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ilẹ̀ yín máa jẹ́ láti aginjù títí dé Lẹ́bánónì àti odò ńlá, ìyẹn odò Yúfírétì, gbogbo ilẹ̀ àwọn ọmọ Hétì,+ títí lọ dé Òkun Ńlá* ní ìwọ̀ oòrùn.*+ Jóṣúà 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.
4 Ilẹ̀ yín máa jẹ́ láti aginjù títí dé Lẹ́bánónì àti odò ńlá, ìyẹn odò Yúfírétì, gbogbo ilẹ̀ àwọn ọmọ Hétì,+ títí lọ dé Òkun Ńlá* ní ìwọ̀ oòrùn.*+
12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.