Ìsíkíẹ́lì 47:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ààlà náà yóò jẹ́ láti òkun dé Hasari-énónì,+ lẹ́bàá ààlà Damásíkù sí àríwá àti ààlà Hámátì.+ Ààlà tó wà ní àríwá nìyí.
17 Ààlà náà yóò jẹ́ láti òkun dé Hasari-énónì,+ lẹ́bàá ààlà Damásíkù sí àríwá àti ààlà Hámátì.+ Ààlà tó wà ní àríwá nìyí.