ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 3:16, 17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Mo sì ti fún àwọn ọmọ Rúbẹ́nì àti àwọn ọmọ Gádì+ ní Gílíádì títí dé Àfonífojì Áánónì, àárín àfonífojì náà sì ni ààlà rẹ̀, títí lọ dé Jábókù, àfonífojì tó jẹ́ ààlà àwọn ọmọ Ámónì, 17 pẹ̀lú Árábà àti Jọ́dánì àti ààlà náà, láti Kínérétì sí Òkun Árábà, Òkun Iyọ̀,* ní ìsàlẹ̀ àwọn gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Písígà sí apá ìlà oòrùn.+

  • Jóṣúà 11:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Gbàrà tí Jábínì ọba Hásórì gbọ́ nípa rẹ̀, ó ránṣẹ́ sí Jóbábù ọba Mádónì,+ sí ọba Ṣímúrónì, ọba Ákíṣáfù,+ 2 àwọn ọba agbègbè olókè tó wà ní apá àríwá, àwọn tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀* apá gúúsù Kínérétì, àwọn tó wà ní Ṣẹ́fẹ́là àti ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Dórì+ ní ìwọ̀ oòrùn,

  • Lúùkù 5:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Nígbà kan tí àwọn èrò ń fún mọ́ ọn, tí wọ́n ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, ó dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ adágún omi Jẹ́nẹ́sárẹ́tì.*+

  • Jòhánù 6:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Lẹ́yìn náà, Jésù gbéra lọ sí òdìkejì Òkun Gálílì tàbí Tìbéríà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́