Jóṣúà 15:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù. 2 Ààlà wọn lápá gúúsù bẹ̀rẹ̀ láti ìkángun Òkun Iyọ̀,*+ láti ibi tí omi ti ya wọ ilẹ̀, tó dojú kọ gúúsù.
15 Ilẹ̀ tí wọ́n pín+ fún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé lọ dé ààlà Édómù,+ aginjù Síínì, dé ìpẹ̀kun Négébù lápá gúúsù. 2 Ààlà wọn lápá gúúsù bẹ̀rẹ̀ láti ìkángun Òkun Iyọ̀,*+ láti ibi tí omi ti ya wọ ilẹ̀, tó dojú kọ gúúsù.