Jóṣúà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Kèké kejì+ wá mú Síméónì, ẹ̀yà Síméónì+ ní ìdílé-ìdílé. Ogún wọn sì wà láàárín ogún Júdà.+