Jóṣúà 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kèké mú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, ilẹ̀ tí wọ́n sì fi kèké pín fún wọn wà láàárín àwọn èèyàn Júdà+ àtàwọn èèyàn Jósẹ́fù.+
11 Kèké mú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, ilẹ̀ tí wọ́n sì fi kèké pín fún wọn wà láàárín àwọn èèyàn Júdà+ àtàwọn èèyàn Jósẹ́fù.+