Jóṣúà 16:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Éfúrémù ní ìdílé-ìdílé nìyí: Ààlà ogún wọn lápá ìlà oòrùn ni Ataroti-ádárì+ títí dé Bẹti-hórónì Òkè,+
5 Ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Éfúrémù ní ìdílé-ìdílé nìyí: Ààlà ogún wọn lápá ìlà oòrùn ni Ataroti-ádárì+ títí dé Bẹti-hórónì Òkè,+