-
Ẹ́kísódù 26:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 “Kí o fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe aṣọ ìdábùú.+ Kí o kó iṣẹ́ sí i lára, kí iṣẹ́ náà jẹ́ àwòrán àwọn kérúbù.
-