Jóṣúà 21:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Torí náà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú yìí+ àtàwọn ibi ìjẹko wọn látinú ogún tiwọn.+
3 Torí náà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fún àwọn ọmọ Léfì ní àwọn ìlú yìí+ àtàwọn ibi ìjẹko wọn látinú ogún tiwọn.+