Jẹ́nẹ́sísì 49:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ègún sì ni fún ìbínú wọn, torí ìkà ni wọ́n fi ṣe àti ìrunú wọn, torí ó le jù.+ Jẹ́ kí n tú wọn ká sí ilẹ̀ Jékọ́bù, kí n sì tú wọn ká sáàárín Ísírẹ́lì.+
7 Ègún sì ni fún ìbínú wọn, torí ìkà ni wọ́n fi ṣe àti ìrunú wọn, torí ó le jù.+ Jẹ́ kí n tú wọn ká sí ilẹ̀ Jékọ́bù, kí n sì tú wọn ká sáàárín Ísírẹ́lì.+