-
Ẹ́kísódù 12:49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Òfin kan náà ni kí ọmọ ìbílẹ̀ àti àjèjì tó ń gbé láàárín yín máa tẹ̀ lé.”+
-
-
Nọ́ńbà 15:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Òfin kan náà àti ìdájọ́ kan náà ni kí ẹ̀yin àti àjèjì tí ẹ jọ ń gbé máa tẹ̀ lé.’”
-