ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 9:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Yàtọ̀ sí ìyẹn, èmi yóò béèrè ẹ̀jẹ̀ yín tó jẹ́ ẹ̀mí yín* pa dà. Èmi yóò béèrè lọ́wọ́ gbogbo ohun alààyè; ọwọ́ kálukú ni màá sì ti béèrè ẹ̀mí arákùnrin rẹ̀.+

  • Ẹ́kísódù 21:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Tí ẹnì kan bá lu èèyàn pa, kí ẹ pa onítọ̀hún.+

  • Léfítíkù 24:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “‘Tí ẹnì kan bá gbẹ̀mí èèyàn,* ẹ gbọ́dọ̀ pa á.+

  • Diutarónómì 19:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 “Àmọ́ tí ọkùnrin kan bá kórìíra ẹnì kejì rẹ̀,+ tó lúgọ dè é, tó ṣe é léṣe,* tó sì kú, tí ọkùnrin náà sì sá lọ sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú yìí, 12 kí àwọn àgbààgbà ìlú rẹ̀ ránṣẹ́ pè é láti ibẹ̀, kí wọ́n sì fà á lé ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ lọ́wọ́, ó gbọ́dọ̀ kú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́