Jóṣúà 20:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Kó máa gbé ìlú náà, títí dìgbà tí wọ́n máa gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú àpéjọ,+ kó sì wà níbẹ̀ títí àlùfáà àgbà tí wọ́n yàn sípò nígbà yẹn fi máa kú.+ Lẹ́yìn náà, apààyàn náà lè pa dà sí ìlú tó ti sá kúrò, ó sì lè wọ ìlú rẹ̀ àti ilé rẹ̀.’”+
6 Kó máa gbé ìlú náà, títí dìgbà tí wọ́n máa gbọ́ ẹjọ́ rẹ̀ níwájú àpéjọ,+ kó sì wà níbẹ̀ títí àlùfáà àgbà tí wọ́n yàn sípò nígbà yẹn fi máa kú.+ Lẹ́yìn náà, apààyàn náà lè pa dà sí ìlú tó ti sá kúrò, ó sì lè wọ ìlú rẹ̀ àti ilé rẹ̀.’”+