Jẹ́nẹ́sísì 9:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹnikẹ́ni tó bá ta ẹ̀jẹ̀ èèyàn sílẹ̀, èèyàn ni yóò ta ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sílẹ̀,+ torí àwòrán Ọlọ́run ni Ó dá èèyàn.+ Ẹ́kísódù 20:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “O ò gbọ́dọ̀ pààyàn.+
6 Ẹnikẹ́ni tó bá ta ẹ̀jẹ̀ èèyàn sílẹ̀, èèyàn ni yóò ta ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ sílẹ̀,+ torí àwòrán Ọlọ́run ni Ó dá èèyàn.+