Ẹ́kísódù 25:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí wọ́n ṣe ibi mímọ́ fún mi, èmi yóò sì máa gbé láàárín* wọn.+ Léfítíkù 26:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Èmi yóò máa rìn láàárín yín, èmi yóò sì jẹ́ Ọlọ́run yín,+ ẹ̀yin ní tiyín, yóò sì jẹ́ èèyàn mi.+