-
Ẹ́kísódù 27:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kí ó ní ogún (20) òpó pẹ̀lú ogún (20) ìtẹ́lẹ̀ oníhò tí wọ́n fi bàbà ṣe. Kí o fi fàdákà ṣe ìkọ́ àwọn òpó náà àti àwọn ohun tó so wọ́n pọ̀.* 11 Kí gígùn àwọn aṣọ ìdábùú tí wọ́n máa ta sí apá àríwá náà jẹ́ ọgọ́rùn-ún (100) ìgbọ̀nwọ́, kí àwọn òpó rẹ̀ jẹ́ ogún (20) àti ogún (20) ìtẹ́lẹ̀ oníhò tí wọ́n fi bàbà ṣe, pẹ̀lú ìkọ́ àwọn òpó náà àti ohun tó so wọ́n pọ̀* tí wọ́n fi fàdákà ṣe.
-