-
Nọ́ńbà 3:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Gbogbo ọmọ Léfì tó jẹ́ ọkùnrin láti ọmọ oṣù kan sókè, tí Mósè àti Áárónì forúkọ wọn sílẹ̀ ní ìdílé-ìdílé, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000).
-
-
Nọ́ńbà 3:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Gbogbo àkọ́bí tó jẹ́ ọkùnrin tí wọ́n forúkọ wọn sílẹ̀ láti ẹni oṣù kan sókè jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlélógún ó lé igba àti mẹ́tàléláàádọ́rin (22,273).
-