-
Nọ́ńbà 2:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Kí ẹ̀yà Gádì wá tẹ̀ lé wọn; Élíásáfù+ ọmọ Rúẹ́lì ni ìjòyè àwọn ọmọ Gádì.
-
-
Nọ́ńbà 7:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan, kí ìjòyè kọ̀ọ̀kan mú ọrẹ rẹ̀ wá fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ náà, ní ọjọ́ kan tẹ̀ lé òmíràn.”
-
-
Nọ́ńbà 7:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Ní ọjọ́ kẹfà, Élíásáfù+ ọmọ Déúélì, ìjòyè àwọn ọmọ Gádì
-
-
Nọ́ńbà 10:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Élíásáfù+ ọmọ Déúélì ni olórí àwùjọ ẹ̀yà àwọn ọmọ Gádì.
-