Ẹ́kísódù 27:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí o ṣe àwọn garawa láti máa fi kó eérú* rẹ̀ dà nù, kí o tún ṣe àwọn ṣọ́bìrì, àwọn abọ́, àwọn àmúga àti àwọn ìkóná, bàbà sì ni kí o fi ṣe gbogbo ohun èlò rẹ̀.+
3 Kí o ṣe àwọn garawa láti máa fi kó eérú* rẹ̀ dà nù, kí o tún ṣe àwọn ṣọ́bìrì, àwọn abọ́, àwọn àmúga àti àwọn ìkóná, bàbà sì ni kí o fi ṣe gbogbo ohun èlò rẹ̀.+