Nọ́ńbà 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí àwọn èèyàn* náà bá fẹ́ gbéra, kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wọlé, kí wọ́n tú aṣọ ìdábùú+ kúrò, kí wọ́n sì fi bo àpótí+ Ẹ̀rí.
5 Tí àwọn èèyàn* náà bá fẹ́ gbéra, kí Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wọlé, kí wọ́n tú aṣọ ìdábùú+ kúrò, kí wọ́n sì fi bo àpótí+ Ẹ̀rí.