-
Nọ́ńbà 7:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 ó sì fún àwọn ọmọ Mérárì ní kẹ̀kẹ́ ẹrù mẹ́rin àti màlúù mẹ́jọ, bí wọ́n ṣe nílò rẹ̀ fún iṣẹ́ wọn, Ítámárì ọmọ àlùfáà Áárónì+ ló ń darí wọn.
-