-
Ẹ́kísódù 27:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Kí ó ní ogún (20) òpó pẹ̀lú ogún (20) ìtẹ́lẹ̀ oníhò tí wọ́n fi bàbà ṣe. Kí o fi fàdákà ṣe ìkọ́ àwọn òpó náà àti àwọn ohun tó so wọ́n pọ̀.*
-