Nọ́ńbà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Àwọn yìí ni wọ́n pè látinú àpéjọ náà. Wọ́n jẹ́ ìjòyè+ nínú ẹ̀yà àwọn bàbá wọn, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ní Ísírẹ́lì.”+
16 Àwọn yìí ni wọ́n pè látinú àpéjọ náà. Wọ́n jẹ́ ìjòyè+ nínú ẹ̀yà àwọn bàbá wọn, olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún ní Ísírẹ́lì.”+