-
Nọ́ńbà 3:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Àwọn ọmọ Kóhátì gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn ni Ámúrámù, Ísárì, Hébúrónì àti Úsíélì.+
-
-
Nọ́ńbà 3:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ọ̀dọ̀ Kóhátì ni ìdílé àwọn ọmọ Ámúrámù ti ṣẹ̀ wá, pẹ̀lú ìdílé àwọn ọmọ Ísárì, ìdílé àwọn ọmọ Hébúrónì àti ìdílé àwọn ọmọ Úsíélì. Ìwọ̀nyí ni ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì.+
-