-
Nọ́ńbà 4:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “Ka àwọn ọmọ Gẹ́ṣónì,+ gẹ́gẹ́ bí agbo ilé bàbá wọn àti ní ìdílé-ìdílé. 23 Kí o forúkọ wọn sílẹ̀, gbogbo àwọn tó jẹ́ ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sí àádọ́ta (50) ọdún, tí wọ́n wà lára àwọn tí a yàn pé kí wọ́n máa ṣiṣẹ́ nínú àgọ́ ìpàdé.
-