Ẹ́kísódù 25:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Kí wọ́n ṣe ibi mímọ́ fún mi, èmi yóò sì máa gbé láàárín* wọn.+ Léfítíkù 26:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá gbé àgọ́ ìjọsìn mi sáàárín yín,+ mi* ò sì ní kọ̀ yín.